adesinaabegunde_yo_eph_text.../06/01.txt

1 line
285 B
Plaintext

\c 6 \v 1 Ẹ̀yin ọmọ, ẹ gbọ́ràn sí àwọn òbí yín nínú Olúwa, nítorí èyí yẹ. \v 2 "Bọ̀wọ̀ fún Bàbá àtí ìyá rẹ" (èyí ni òfin kinní pẹ̀lú ìlérí). \v 3 "Kí ó lè dára fún yín, kí ẹ sì leè ní ẹ̀mí gígùn nínú ayé."