adesinaabegunde_yo_eph_text.../06/19.txt

1 line
338 B
Plaintext

\v 19 Ki ẹ si gbadura fun mi, pe ki a lee fun mi ni isẹ iransẹ kan nigbati mo ba ya ẹnu mi. Ẹ gbadura pe ki n lee ma sọọ di mimọ pẹlu igboya a`wọn otito naa ti o pamọ nipa iyinrere. \v 20 Nitori iyinrere ni mo se di ikọ ti a pamọ ninu ide, ki n lee maa sọọ pẹlu igboya, gẹgẹbi o se ye ki n sọrọ.