adesinaabegunde_yo_eph_text.../05/18.txt

1 line
536 B
Plaintext

\v 18 Ẹ má sì se fi ara yín fún ọtí mímu, nítorí èyí á mú kí ènìyàn si ìwà hù, sùgbọ́n ẹ kúkú máa kún fún Ẹ̀mímímọ́. \v 19 Kí ẹ má bá ara yín sọ̀rọ̀ pẹ̀lú orin Psáàlmù àti àwọn orin, àti orin ẹ̀mi, kí ẹ máa kọ́ orin nínú ẹ̀mí sí Olúwa láti inú ọkàn yín wá. \v 20 Ẹ máa dúpẹ́ fún ohun gbogbo ní orúkọ Olúwa wa Jésù Krístì sí Ọlọ́run Baba náà. \v 21 Ẹ máa tẹríba fún ara yín pẹ̀lu ọ̀wọ̀ fún Krístì.