adesinaabegunde_yo_eph_text.../05/15.txt

1 line
324 B
Plaintext

\v 15 Ẹ se àkíyèsí bí ẹ se ń gbé igbé ayé yín - kìí se gẹ́gẹ́bí àwọn aláìgbọ́n sùgbọ́n bí ọlọgbọ́n, \v 16 Ẹ ra ìgbà padà nítorí búburú ni àwọn ọjọ́. \v 17 Nítorínáà, ẹ máse se òmùgọ̀, sùgbọ́n ẹ ní òye ohun tí ìfẹ́ Ọlọ́run jẹ́.