adesinaabegunde_yo_eph_text.../05/08.txt

1 line
552 B
Plaintext

\v 8 Nítorí ní ìgbàkan rí òkùnkùn ni yín, sùgbọ́n nísinsìnyí, ìmọ́lẹ̀ ni yín nínú Olúwa. Ẹ rìn gẹ́gẹ́bí ọmọ ìmọ́lẹ̀. ní yín, sùgbọ́n nísinsìnyí \v 9 (Nítorí èso ìmọ́lẹ̀ kún fún ìserere, òdodo, àti òtítọ́). \v 10 Kí ẹ sì máa wádì ohun tí ó wu Olúwa. \v 11 Ẹ máse darapọ̀ mọ́ àíleso isẹ́ òkùnkùn, sùgbọ́n ẹ kúkú máa se àfihàn wọn. \v 12 Nítorí ohun itìjú ni láti máa dárúkọ ohun tí wọ́n ńse ní ìkọ̀kọ̀.