adesinaabegunde_yo_eph_text.../05/05.txt

1 line
438 B
Plaintext

\v 5 Kí èyí kí ó dá yín lójú, kò sí alágbèrè, aláìmọ́, tàbí oníjẹkújẹ kan - tí í se abọ̀rìsà - tí yóò ní ìpín kan ní ìjọba Krístì àti ti Ọlọ́run. \v 6 Kí ẹnikẹ́ni máse tàn yín jẹ pẹ̀lú ọọ̀rọ̀ kòròfo nítorí nkan wọ̀nyí ni ìbínú Ọlọ́run se ḿbọ̀ wá sórí àwọn ọmọ aláìgbọràn. \v 7 Nítorínáà ẹ mase darapọ̀ mọ́ wọn.