adesinaabegunde_yo_eph_text.../05/03.txt

1 line
418 B
Plaintext

\v 3 Sùgbọ́n, kò gbọdọ̀ sí àmọ̀ràn kan nípa ìwà ìbàjẹ́ tí ìbánilòpọ̀, tàbí irúfẹ́ ìwà ìdọ̀tí tàbí ìjẹkújẹ, nítorí èyí kò tọ́ fún àwọn ènìyàn, Ọlọ́run mímọ́. \v 4 Kó má se sí èérí, kó má se sí ọ̀rọ̀ àlùfànsá tàbí àwọn àwàdà tí ó le - gbogbo àwọn tí kò tọ́, bíbẹ̀kọ́ ó yẹ kí á máa dúpẹ́.