1 line
578 B
Plaintext
1 line
578 B
Plaintext
\v 19 Nítorínáà nísinsìnyí, ẹ̀yin Kèfèrí kìí se àlejò àti àjèjì mọ dipo bẹ́ẹ̀ ẹ ti di ọmọ ìbílẹ̀ kanna pẹ̀lú àwọn ènìyàn mímọ àti ọmọ agbo ile Ọlọ́run. \v 20 A ti kó yin lé orí ìpìlẹ̀ àwọn Aposteli àti àwọn wóòli, ati Kristi Jesu funrarẹ si ni okuta igun ilé. \v 21 Nínú Rẹ gbogbo ilé ẹ di ara won papo, o si n dagba gẹ́gẹ́bí Tẹ́mpìlì nínú Oluwa. \v 22 Nínú Rẹ̀ ni a ti ń kọ́ ẹ̀yín pẹ̀lú papo gẹ́gẹ́bí ibùgbé fún Ọlọ́run nínú Ẹ̀mí. |