adesinaabegunde_yo_eph_text.../02/04.txt

2 lines
638 B
Plaintext

\v 4 Sùgbọ́n Ọlọ́run nínú ọrọ̀ àánú Rẹ̀, àti nítorí ìfẹ́ Rẹ̀ títóbi, tí ó fi fẹ́ wa. \v 5 Nígbàtí a ti kú nínú ìrékojá ó mú wa wà láàyè papọ̀ nínú Krístì, nípa ore ọ̀fẹ́ a gbà yín là. \v 6 Ọlọ́run jí wa dìde papọ̀ pẹ̀lú Krístì, Ọlọ́run sí mú wa jókò papọ̀ nínú àwọn ọ̀run nínú Krístì Jesu.
su. \v 7 Ki o ba le jẹ́ wípeeé ni ayé ti ḿbọ̀, kí òhun kí ó leè fihàn wa , ọrọ̀ àánú Rẹ̀ tí ó tóbi láìlósùnwọ̀n ore ọ̀fẹ́ tí ó ti sọ nípa inú rere Rẹ̀ sí wa nínú Krístì Jésù.