adesinaabegunde_yo_eph_text.../01/15.txt

1 line
282 B
Plaintext

\v 15 Fún ìdí èyí, láti ìgbà tí mo ti gbọ́ nípa ìgbàgbọ́ yín nínú Olúwa Jésù àti ìfẹ́ yín fún gbogbo àwon ènìyàn mímọ́. \v 16 N kò tíì dẹ́kun láti dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run bí mo se n dárúko yín nínú àwon àdúrà mi.