adesinaabegunde_yo_eph_text.../06/21.txt

1 line
302 B
Plaintext

\v 21 Tíkíkù, arákùnrin olùfẹ́, àti ìránsẹ́ olòótọ́ nínú Olúwa, yóò sọ ohun gbogbo fún yín, kí ẹ̀yin kí ó leè mọ̀ bí mo se ń se. \v 22 Mo ti rán an sí yín nítorí ìdí èyí, kí ẹ leè mọ̀ bí a se wà, kí òun kí ó leè mú yín lọ́kàn le.