adesinaabegunde_yo_eph_text.../06/17.txt

1 line
375 B
Plaintext

\v 17 Ẹ sì mú akoto ìgbàlà àti idà ẹ̀mí, tíí se ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. \v 18 Pẹ̀lú gbogbo àdúrà àti ìsìpẹ̀, ẹ gbadúrà ní ìgbà gbogbo nínú Ẹ̀mí. Pẹ̀lú ọkàn yìí, ẹ má sọ́nà ní ìgbà gbogbo pẹ̀lú ìpamọ́ra gbogbo, gẹ́gẹ́bí ẹ se ń gbàdúrà fún gbogbo àwọn ènìyàn, Ọlọ́run, mímọ́