adesinaabegunde_yo_eph_text.../06/05.txt

1 line
769 B
Plaintext

\v 5 Ẹ̀yin ọmọ ọ̀dọ̀, ẹ gbọ́ràn sí àwọn ọ̀gá yín nínú ayé pẹ̀lú ọ̀wọ̀ tí jinlẹ̀ àti ìwárìrì, nínú òtítọ́ ọkàn yín, Ẹ gbọ́ràn sí won bí ẹ ó se gbọ́ràn sí Krístì. \v 6 .Ẹ gbọ́ràn, kìí se nígbàtí ọ̀gá ń wò yín, kí ẹ ba leè mú inú wọn dùn, bíkòse pé kí ẹ gbọ́ràn bí ọmọ ọ̀dọ̀ Krístì, tí ó ń se ìfẹ́ Ọlọ́run láti inú ọkàn rẹ̀. \v 7 Ẹ se isẹ́ yín pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín, gẹ́gẹ́bí ẹnití ń sisẹ́ fún Olúwa tí kìí sì se ènìyàn. \v 8 Nítorí àwa mọ̀ pé ohun rere kóhun rere tí ẹnìkọ̀ọ̀kan bá se, yóò gbà èrè lọ́wọ́ Olúwa, ìbá se ẹrú tàbí òmìnira.