adesinaabegunde_yo_eph_text.../05/28.txt

1 line
381 B
Plaintext

\v 28 Bákannáà àwọn ọkọ yẹ kí wọ́n fẹ́ràn àwọn aya wọn gẹ́gẹ́bí ara àwọn tìkárawọn. \v 29 Nítorí kò sí ẹnití ó jẹ́ kórira ara òun tìkárarẹ̀, bíkòse kí ó máa kẹ́ẹ, àti se ìtọ́jú rẹ̀, gẹ́gẹ́bí Krístì se ń kẹ́ ìjọ tí ó sì n tọ́jú rẹ̀. \v 30 Nítorí ẹ̀yà ara Rẹ̀ ni àwa.