adesinaabegunde_yo_eph_text.../03/14.txt

1 line
337 B
Plaintext

\v 14 Nítorí ìdí èyí, mo wà lórí orúnkún mi sí Baba. \v 15 Láti ọ̀dọ̀ ẹnití a ti sọ gbogbo ìdílé ní Ọ̀run àti ní aye ní orúkọ. \v 16 Mo gbàdúrà pé kí O fifún yín gẹ́gẹ́bí ọrọ̀ ògo Rẹ̀, kí ó fún yín ní okun pẹ̀lú agbára nípa Ẹ̀mí Rẹ̀ tí ó wà nínú yín.