adesinaabegunde_yo_eph_text.../03/08.txt

1 line
510 B
Plaintext

\v 8 Ọlọ́run fún mí ní ẹ̀bùn yìí bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èmi ni ó kéré jù nínú àwon ènìyàn, Ọlọ́run, mímọ́. Ẹ̀bùn yìí ni wípé, mo gbọ́dọ̀ kéde ìjìnlẹ̀ ọ̀rọ̀ ìhìnrere Krístì sí àwon Kèfèrí. \v 9 Ẹ̀bùn Ọlọ́run fún mi ní wípé n gó mú ẹnìkọ̀kan wá sínú ìmọ́lẹ̀ ohun tí ète Ọlọ́run jẹ́. Ète yìí tí wà nínú ìpamọ́ láti aìmoye ọdún sẹ́yìn nípa Ọlọ́run tí ó dá ohun gbogbo.