adesinaabegunde_yo_eph_text.../03/06.txt

1 line
357 B
Plaintext

\v 6 Òtítọ́ tí ó pamọ́ yìí ni wípé, àwọn kèfèrí pẹ̀lú àwọn ajogún àti àwọn akẹgbẹ́, àti pé wọ́n pín nínú ìlèrí tí ó wà nínú Krístì Jésù nípa ti ìhìnrere náà. \v 7 Nítorí mo di ìránsẹ́ ìhìnrere nípa ẹ̀bùn ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run tí a fi fún mi nípa isẹ́ agbára Rẹ̀.