adesinaabegunde_yo_eph_text.../01/07.txt

1 line
244 B
Plaintext

\v 7 Nínú Jésù Krístì àwá ni ìràpadà nípa ẹ̀jẹ̀ àti nípa ìdáríjìn ẹ̀sẹ̀ wa gbogbo nípa ọ̀rọ̀ ore ọ̀fẹ́ Rẹ̀. \v 8 Ó tú ore ọ̀fẹ́ Rẹ̀ lé wa lórí pẹ̀lú gbogbo ọgbọ́n àti òye.