\v 9 Ẹ̀yin ọ̀gá, ẹ tọ́jú àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ bákannáà. Ẹ máse halẹ̀ mọ́ won. Ẹ kúkú mọ̀ wípé ọ̀gá ẹ̀yin méjèjì wa ni ọrun, ko si si ojusaaju pẹlu Rẹ̀