\v 21 Tikiku, arakunrin olufẹ, ati iransẹ olootọ ninu Oluwa, yoo sọ ohun gbogbo fun yin, ki ẹyin ki o lee mọ bi mo se n se. \v 22 Mo ti ran an si yin nitori idi eyi, ki ẹ lee mọ bi a se wa, ki ohun ki o lee mu yin lọkan le.