\v 13 Sùgbọ́n nígbàtí ìmọ́lẹ̀ bá tàn, á fi ìríran hàn. \v 14 Nítorí´ ohun tí ó bá hàn ni ìmọ́lẹ̀. Nítorínáà ó wípé: "Jí ìwọ Olóorun, kí o sì dìde láàrin àwọn òkú, Krístì yóò tàn sí ọ.