Thu Jun 27 2019 21:02:31 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 21:02:34 +01:00
parent af45ae63ec
commit fefc783048
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 19 Nínú àdúrà mi, mo béèrè wípé kí ẹ̀yin kí ó lè mọ títóbi agbára Rẹ̀ tí kó ní òsùnwọ̀n nínú àwa tí ó gbàgbọ́ gẹ́gẹ́bí síse isẹ́ títóbi nípa okun Rẹ̀. \v 20 Èyí ni òduwọ̀n agbára kannà tí Ọlọ́run fi sisẹ́ nínú Krístì, nígbàtí Ó jíi dìde nínú àwọn òkú tí ó sì mú kí ó jòkó ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀ nínú àwon ọ̀run. \v 21 Ó mú kí Krístì jòkó rékọjá gbogbo ìsàkoso àti àsẹ àti agbára, àti ìjọba àti orúkọ kórukọ́ tí a lè dá. Krístì yóò se àkoso, kìí se ni aye yii nikan sugbon, koda ni aye ti mbo pelu.
\v 19 Nínú àdúrà mi, mo béèrè wípé kí ẹ̀yin kí ó lè mọ títóbi agbára Rẹ̀ tí kó ní òsùnwọ̀n nínú àwa tí ó gbàgbọ́ gẹ́gẹ́bí síse isẹ́ títóbi nípa okun Rẹ̀. \v 20 Èyí ni òduwọ̀n agbára kannà tí Ọlọ́run fi sisẹ́ nínú Krístì, nígbàtí Ó jíi dìde nínú àwọn òkú tí ó sì mú kí ó jòkó ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀ nínú àwon ọ̀run. \v 21 Ó mú kí Krístì jòkó rékọjá gbogbo ìsàkoso àti àsẹ àti agbára, àti ìjọba àti orúkọ kórukọ́ tí a lè dá. Krístì yóò se àkoso, kìí se ní ayé yìí nìkan ṣùgbọ́n, kódà ní ayé tí ḿbọ̀ pẹ̀lú.

View File

@ -1 +1 @@
\v 22 Olorun fi ohun gbogbo si abe ese Kristi, O si fi I fun ijo gegebi Ori ohun gbogbo. \v 23 Ijo je ara Re, kikun eniti o kun ohun gbogbo ninu ohun gbogbo.
\v 22 Ọlọ́run fi ohun gbogbo si abe ese Kristi, O si fi I fun ijo gegebi Ori ohun gbogbo. \v 23 Ijo je ara Re, kikun eniti o kun ohun gbogbo ninu ohun gbogbo.