Thu Jun 27 2019 21:19:50 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 21:19:53 +01:00
parent 4997a6f850
commit c6610ab638
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\c 2 \v 1 Sùgbọ́n nípa ti yín, ẹ̀yin ti kú nínú ẹsẹ àti ìrékojá yín. \v 2 Nínú ẹ̀sẹ̀ àti ìrékojá wọ̀nyí ni ẹ ń gbé gẹ́gẹ́bí ìse ti ayé yǐ. Ẹ̀yin ńgbé ayé gẹ́gẹ́bí fún alákoso àti àwon alásẹ òfurufu, emi naa ti nsise ninu awon omo l=alaigboran. \v 3 Nigba kan ri, gbogbo wa n gbe laarin awon eniyan wonyi, nipa mimu ife buruku ti eda ese wa sisise, ati lati maa mu ife ti ara ati ti okan wa si imuse. Nipa iseda omo ibinu, gegebi gbogbo eda eniyan.
\c 2 \v 1 Sùgbọ́n nípa ti yín, ẹ̀yin ti kú nínú ẹsẹ àti ìrékojá yín. \v 2 Nínú ẹ̀sẹ̀ àti ìrékojá wọ̀nyí ni ẹ ń gbé gẹ́gẹ́bí ìse ti ayé yǐ. Ẹ̀yin ńgbé ayé gẹ́gẹ́bí fún alákoso àti àwon alásẹ òfúrufú, èmi náà tí ńsisẹ́ nínú àwọn ọmọ aláìgbọràn. \v 3 Nigba kan ri, gbogbo wa n gbe laarin awon eniyan wonyi, nipa mimu ife buruku ti eda ese wa sisise, ati lati maa mu ife ti ara ati ti okan wa si imuse. Nipa iseda omo ibinu, gegebi gbogbo eda eniyan.