diff --git a/05/08.txt b/05/08.txt index 85707d1..b85f551 100644 --- a/05/08.txt +++ b/05/08.txt @@ -1 +1 @@ -\v 8 Nítorí ní ìgbàkan rí òkùnkùn ni yín, sùgbọ́n nísinsìnyí, ìmọ́lẹ̀ ni yín nínú Olúwa. Ẹ rìn gẹ́gẹ́bí ọmọ ìmọ́lẹ̀. ní yín, sùgbọ́n nísinsìnyí \v 9 (Nítorí èso ìmọ́lẹ̀ kún fun iserere, ododo, ati otito). \v 10 Ki ẹ si maa wadi ohun ti o wu Oluwa. \v 11 Ẹ mase darapọ mọ aileso isẹ okunkun, sugbọn ẹ kuku maa se afihan wọn. \v 12 Nitorí ohun itiju ni lati maa darukọ ohun ti won se ni ikọkọ. \ No newline at end of file +\v 8 Nítorí ní ìgbàkan rí òkùnkùn ni yín, sùgbọ́n nísinsìnyí, ìmọ́lẹ̀ ni yín nínú Olúwa. Ẹ rìn gẹ́gẹ́bí ọmọ ìmọ́lẹ̀. ní yín, sùgbọ́n nísinsìnyí \v 9 (Nítorí èso ìmọ́lẹ̀ kún fún ìserere, òdodo, àti òtítọ́). \v 10 Kí ẹ sì máa wádì ohun tí ó wu Olúwa. \v 11 Ẹ máse darapọ̀ mọ́ aleso isẹ okunkun, sugbọn ẹ kuku maa se afihan wọn. \v 12 Nitorí ohun itiju ni lati maa darukọ ohun ti won se ni ikọkọ. \ No newline at end of file