Sat Aug 03 2019 02:04:41 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-08-03 02:04:44 +01:00
parent b70191be8b
commit 948a56957d
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 8 Nítorí ní ìgbàkan rí òkùnkùn ni yín, sùgbọ́n nísinsìnyí, ìmọ́lẹ̀ ni yín nínú Olúwa. Ẹ rìn gẹ́gẹ́bí ọmọ ìmọ́lẹ̀. ní yín, sùgbọ́n nísinsìnyí \v 9 (Nítorí èso ìmọ́lẹ̀ kún fún ìserere, òdodo, àti òtítọ́). \v 10 Kí ẹ sì máa wádì ohun tí ó wu Olúwa. \v 11 Ẹ máse darapọ̀ mọ́ aleso isẹ okunkun, sugbọn ẹ kuku maa se afihan wọn. \v 12 Nitorí ohun itiju ni lati maa darukọ ohun ti won se ni ikọkọ.
\v 8 Nítorí ní ìgbàkan rí òkùnkùn ni yín, sùgbọ́n nísinsìnyí, ìmọ́lẹ̀ ni yín nínú Olúwa. Ẹ rìn gẹ́gẹ́bí ọmọ ìmọ́lẹ̀. ní yín, sùgbọ́n nísinsìnyí \v 9 (Nítorí èso ìmọ́lẹ̀ kún fún ìserere, òdodo, àti òtítọ́). \v 10 Kí ẹ sì máa wádì ohun tí ó wu Olúwa. \v 11 Ẹ máse darapọ̀ mọ́ àíleso isẹ́ òkùnkùn, sùgbọ́n ẹ kúkú máa se àfihàn wọn. \v 12 Nítorí ohun itìjú ni láti máa dárúkọ ohun tí won se ni ikọkọ.