diff --git a/02/19.txt b/02/19.txt index eaecf9f..c6f63b4 100644 --- a/02/19.txt +++ b/02/19.txt @@ -1 +1 @@ -\v 19 Nítorínáà nísinsìnyí, ẹ̀yin Kèfèrí kìí se àlejò àti àjèjì mọ dipo bẹ́ẹ̀ ẹ ti di ọmọ ìbílẹ̀ kanna pẹ̀lú àwọn ènyan mimo ati omo agbo ile Olorun. \v 20 A ti ko yin le ori ipile awon Aposteli ati awon wooli, ati Kristi Jesu funrare si ni okuta igun ile. \v 21 Ninu Re gbogbo ile di ara won papo, o si n dagba gegebi Tempili ninu Oluwa. \v 22 Ninu Re ni a ti n ko eyin pelu papo gegebi ibugbe fun Olorun ninu Emi. \ No newline at end of file +\v 19 Nítorínáà nísinsìnyí, ẹ̀yin Kèfèrí kìí se àlejò àti àjèjì mọ dipo bẹ́ẹ̀ ẹ ti di ọmọ ìbílẹ̀ kanna pẹ̀lú àwọn ènìyàn mímọ àti ọmọ agbo ile Ọlọ́run. \v 20 A ti kó yin lé orí ìpìlẹ̀ àwọn Aposteli ati awon wooli, ati Kristi Jesu funrare si ni okuta igun ile. \v 21 Ninu Re gbogbo ile di ara won papo, o si n dagba gegebi Tempili ninu Oluwa. \v 22 Ninu Re ni a ti n ko eyin pelu papo gegebi ibugbe fun Olorun ninu Emi. \ No newline at end of file