Thu Jun 27 2019 22:33:51 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 22:33:52 +01:00
parent 3c2fa51455
commit 6e8224ba57
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 13 Sùgbọ́n nísinsìnyí nínú Krístì Jésù ẹ̀yin tí ó ti jìnnà réré nígbàkanrí sí Ọlọ́run, ẹ̀jẹ̀ Jésù ti mú yín wá sí ìtòsí. \v 14 Nítorí ohun ni àláfìa wa. O ti so awon mejieji di eyokan, nipa ara Re, o ti wo ogiri ikorira, isota ti o pin wa niya. \v 15 Eyi ni wipe, o pa ofin, ase atowodowo run ki o ba le ota okunrin titun kan ninu ara Re, ki o ba le se alafia. \v 16 Kristi se ilaja awon eniyan sinu ara kan si Olorun nipase agbelebu, o ti pa ikorira.
\v 13 Sùgbọ́n nísinsìnyí nínú Krístì Jésù ẹ̀yin tí ó ti jìnnà réré nígbàkanrí sí Ọlọ́run, ẹ̀jẹ̀ Jésù ti mú yín wá sí ìtòsí. \v 14 Nítorí ohun ni àláfìa wa. Ó ti sọ àwon mejèjì di ẹyọkan, nípa ara Rẹ̀, ó ti wó ògiri ìkórira, isọ̀ta ti o pin wa niya. \v 15 Eyi ni wipe, o pa ofin, ase atowodowo run ki o ba le ota okunrin titun kan ninu ara Re, ki o ba le se alafia. \v 16 Kristi se ilaja awon eniyan sinu ara kan si Olorun nipase agbelebu, o ti pa ikorira.