Thu Jun 27 2019 22:41:51 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 22:41:52 +01:00
parent 76b27b2ecd
commit 6c71f5d88e
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 13 Sùgbọ́n nísinsìnyí nínú Krístì Jésù ẹ̀yin tí ó ti jìnnà réré nígbàkanrí sí Ọlọ́run, ẹ̀jẹ̀ Jésù ti mú yín wá sí ìtòsí. \v 14 Nítorí ohun ni àláfìa wa. Ó ti sọ àwon mejèjì di ẹyọkan, nípa ara Rẹ̀, ó ti wó ògiri ìkórira, ìsọ̀tá tí ó pín wa níyà. \v 15 Èyí ní wípé, ó pa òfin, àsẹ àtọwọ́dọ́wọ́ run kí ó ba lé ọ̀tá okùnrin titun kan nínú ara Rẹ̀, kí ó ba le se aláfìa. \v 16 Krístì se ìlàjà àwọn ènìyàn sínú ara kan sí Ọlọ́run nípasẹ̀ àgbèlébù, o ti pa ikorira.
\v 13 Sùgbọ́n nísinsìnyí nínú Krístì Jésù ẹ̀yin tí ó ti jìnnà réré nígbàkanrí sí Ọlọ́run, ẹ̀jẹ̀ Jésù ti mú yín wá sí ìtòsí. \v 14 Nítorí ohun ni àláfìa wa. Ó ti sọ àwon mejèjì di ẹyọkan, nípa ara Rẹ̀, ó ti wó ògiri ìkórira, ìsọ̀tá tí ó pín wa níyà. \v 15 Èyí ní wípé, ó pa òfin, àsẹ àtọwọ́dọ́wọ́ run kí ó ba lé ọ̀tá okùnrin titun kan nínú ara Rẹ̀, kí ó ba le se aláfìa. \v 16 Krístì se ìlàjà àwọn ènìyàn sínú ara kan sí Ọlọ́run nípasẹ̀ àgbèlébù, ó ti pa ìkórira.

View File

@ -1 +1 @@
\v 17 Jesu wa, o polongo alafia fun eyin ti o wa ni ona jijin rere ati alafia fun awon ti o wa ni itosi. \v 18 Nitori nipase Jesu, gbogbo wa ni ona si ipa emi kan si odo Baba.
\v 17 Jésù wá, ó polongo àlàfia fun eyin ti o wa ni ona jijin rere ati alafia fun awon ti o wa ni itosi. \v 18 Nitori nipase Jesu, gbogbo wa ni ona si ipa emi kan si odo Baba.