Thu Jul 18 2019 06:03:44 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-07-18 06:03:46 +01:00
parent 276a13df95
commit 6be19b511b
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 3 Mo n kowe gegebi ifihan ti a mu ki n mo. Eyi ni otito ti o pamo, ti mo kowe re si yin ni kia.\v 4 Nigbati e ba ka eyi, yoo le ye yin, oye ti mo ni nipa otito ti o pamo nipa Kristi. \v 5 Ni won iran miran, otito yi ko di mimo si awon omo eniyan. Sugbon nisinsinyi, o ti di fifihan nipa Emi si awon aposteli ati wooli ti a ya soto fun ise yi.
\v 3 Mo ń kọ̀wé gẹ́gẹ́bí ìfihàn tí a mú kí n mọ̀. Èyi ni otito ti o pamo, ti mo kowe re si yin ni kia.\v 4 Nigbati e ba ka eyi, yoo le ye yin, oye ti mo ni nipa otito ti o pamo nipa Kristi. \v 5 Ni won iran miran, otito yi ko di mimo si awon omo eniyan. Sugbon nisinsinyi, o ti di fifihan nipa Emi si awon aposteli ati wooli ti a ya soto fun ise yi.