Thu Jun 27 2019 22:47:51 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 22:47:53 +01:00
parent d246fc6308
commit 4b18faae07
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 19 Nitorinaa nisinsinyi, eyin keferi kii se alejo ati ajeji mo dipo bee e ti di omo ibile kanna pelu awon eniyan mimo ati omo agbo ile Olorun. \v 20 A ti ko yin le ori ipile awon Aposteli ati awon wooli, ati Kristi Jesu funrare si ni okuta igun ile. \v 21 Ninu Re gbogbo ile di ara won papo, o si n dagba gegebi Tempili ninu Oluwa. \v 22 Ninu Re ni a ti n ko eyin pelu papo gegebi ibugbe fun Olorun ninu Emi.
\v 19 Nítorínáà nísinsìnyí, ẹ̀yin Kèfèrí kìí se àlejò àti àjeji mo dipo bee e ti di omo ibile kanna pelu awon eniyan mimo ati omo agbo ile Olorun. \v 20 A ti ko yin le ori ipile awon Aposteli ati awon wooli, ati Kristi Jesu funrare si ni okuta igun ile. \v 21 Ninu Re gbogbo ile di ara won papo, o si n dagba gegebi Tempili ninu Oluwa. \v 22 Ninu Re ni a ti n ko eyin pelu papo gegebi ibugbe fun Olorun ninu Emi.