Mon Jun 24 2019 22:15:22 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-24 22:15:25 +01:00
parent 18d2833055
commit 1c9bf9c6ef
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 19 \v 20 Eyi ni oduwon agbara kanna ti Olorun fi sise ninu Kristi, nigbati O jii dide ninu awon oku ti o si mu ki o joko ni owo otu \v 21 O mu ki Krisiti joko rekoja gbogbo isakoso ati ase ati agbara, ati ijoba ati oruko ko ruko ti a le da. Kristi yoo se akoso, kii se ni aye yii nikan sugbon, koda ni aye ti mbo pelu.
\v 19 Ninu adura mi, mo beere wipe ki eyin ki o le mo titobi agbara Re ti ko ni osunwon ninu awa ti o gbagbo gegebi sise ise titobi nipa okun Re. \v 20 Eyi ni oduwon agbara kanna ti Olorun fi sise ninu Kristi, nigbati O jii dide ninu awon oku ti o si mu ki o joko ni owo otun Re ninu awon orun. \v 21 O mu ki Krisiti joko rekoja gbogbo isakoso ati ase ati agbara, ati ijoba ati oruko ko ruko ti a le da. Kristi yoo se akoso, kii se ni aye yii nikan sugbon, koda ni aye ti mbo pelu.