From 1a789c2afa7c19e75425b8f80ab7138c4ceafb34 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Thu, 27 Jun 2019 22:27:52 +0100 Subject: [PATCH] Thu Jun 27 2019 22:27:51 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 02/11.txt | 2 +- 02/13.txt | 2 +- 2 files changed, 2 insertions(+), 2 deletions(-) diff --git a/02/11.txt b/02/11.txt index 0efa56d..95ba9c9 100644 --- a/02/11.txt +++ b/02/11.txt @@ -1 +1 @@ -\v 11 Nítorínaáà ẹ rántí wípé nígbàkan rí, ẹ jẹ́ kèfèrí nínú ara. A pè yín ní "aláìkọ̀là" nípa ohun tí a pè ní "ìkọ̀là" nínú ara tí a se nípa ọwọ́ ènìyàn. \v 12 Ní ìgbànáà ẹ wà ní ìyapa pẹ̀lú Krístì. Ẹ jẹ́ àlejò sí àwọn ara Isrẹlì. Ẹ jẹ́ àlejò sí majẹ̀mu náà tí a ti se ìlérí. Ẹ kò ní ìrètí kan fún ọjọ́ ọ̀la, Ẹ si wa laini Olorun ninu aye. \ No newline at end of file +\v 11 Nítorínaáà ẹ rántí wípé nígbàkan rí, ẹ jẹ́ kèfèrí nínú ara. A pè yín ní "aláìkọ̀là" nípa ohun tí a pè ní "ìkọ̀là" nínú ara tí a se nípa ọwọ́ ènìyàn. \v 12 Ní ìgbànáà ẹ wà ní ìyapa pẹ̀lú Krístì. Ẹ jẹ́ àlejò sí àwọn ara Isrẹlì. Ẹ jẹ́ àlejò sí majẹ̀mu náà tí a ti se ìlérí. Ẹ kò ní ìrètí kan fún ọjọ́ ọ̀la, Ẹ sì wà láìní Ọlọ́run nínú ayé. \ No newline at end of file diff --git a/02/13.txt b/02/13.txt index d84837e..b929100 100644 --- a/02/13.txt +++ b/02/13.txt @@ -1 +1 @@ -\v 13 Sugbon nisinsinyi ninu Kristi Jesu eyin ti o ti jinna rere nigbakanri si Olorun, eje Jesu ti mu yin wa si itosi. \v 14 Nitori ohun ni alafia wa. O ti so awon mejieji di eyokan, nipa ara Re, o ti wo ogiri ikorira, isota ti o pin wa niya. \v 15 Eyi ni wipe, o pa ofin, ase atowodowo run ki o ba le ota okunrin titun kan ninu ara Re, ki o ba le se alafia. \v 16 Kristi se ilaja awon eniyan sinu ara kan si Olorun nipase agbelebu, o ti pa ikorira. \ No newline at end of file +\v 13 Sùgbọ́n nísinsinyi ninu Kristi Jesu eyin ti o ti jinna rere nigbakanri si Olorun, eje Jesu ti mu yin wa si itosi. \v 14 Nitori ohun ni alafia wa. O ti so awon mejieji di eyokan, nipa ara Re, o ti wo ogiri ikorira, isota ti o pin wa niya. \v 15 Eyi ni wipe, o pa ofin, ase atowodowo run ki o ba le ota okunrin titun kan ninu ara Re, ki o ba le se alafia. \v 16 Kristi se ilaja awon eniyan sinu ara kan si Olorun nipase agbelebu, o ti pa ikorira. \ No newline at end of file