Thu Jun 27 2019 22:07:50 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 22:07:52 +01:00
parent dc2ee1cc10
commit 0cebb7a5f0
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1,2 +1,2 @@
\v 4 Sùgbọ́n Ọlọ́run nínú ọrọ̀ àánú Rẹ̀, àti nítorí ìfẹ́ Rẹ̀ títóbi, tí ó fi fẹ́ wa. \v 5 Nígbàtí a ti kú nínú ìrékojá ó mú wa wà láàyè papọ̀ nínú Krístì, nípa ore ọ̀fẹ́ a gbà yín là. \v 6 Ọlọ́run jí wa dìde papọ̀ pẹ̀lú Krístì, Ọlọ́run sí mú wa jókò papọ̀ nínú àwọn ọ̀run nínú Krístì Jesu.
su. \v 7 Ki o ba le jẹ́ wípeeé ni ayé ti ḿbọ̀, kí òhun kí ó leè fihàn wa , ọrọ̀ àánú Rẹ̀ tí ó tóbi lailosùnwọ̀n oore ofe ti o ti so nipa inu rere Re si wa ninu Kristi Jesu.
su. \v 7 Ki o ba le jẹ́ wípeeé ni ayé ti ḿbọ̀, kí òhun kí ó leè fihàn wa , ọrọ̀ àánú Rẹ̀ tí ó tóbi láìlósùnwọ̀n ore ọ̀fẹ́ tí ó ti sọ nípa inú rere Rẹ̀ sí wa nínú Krístì Jesu.