Sat Aug 03 2019 02:22:41 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-08-03 02:22:44 +01:00
parent 4faf787b54
commit 06b580292d
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Ẹ má sì se fi ara yín fún ọti mimu, nitori eyi a mu ki eniyan si iwa hu, sugbọn ẹ kuku maa kun fun Ẹmimimọ. \v 19 Ki ẹ ma ba ara yin sọrọ pẹlu orin Psalmu ati awọn orin, ati orin ẹmi, ki ẹ maa kọ orin ninu ẹmi si Oluwa lati inu ọkan yin wa. \v 20 Ẹ maa dupẹ fun ohun gbogbo ni orukọ Oluwa wa Jesu Kristi si Ọlọrun Baba náà. \v 21 Ẹ maa tẹriba fun ara yin pẹlu ọwọ fun Kristi.
\v 18 Ẹ má sì se fi ara yín fún ọtí mímu, nítorí èyí á mú kí ènìyàn si ìwà hù, sùgbọ́n ẹ kúkú máa kún fún Ẹ̀mmimọ. \v 19 Ki ẹ ma ba ara yin sọrọ pẹlu orin Psalmu ati awọn orin, ati orin ẹmi, ki ẹ maa kọ orin ninu ẹmi si Oluwa lati inu ọkan yin wa. \v 20 Ẹ maa dupẹ fun ohun gbogbo ni orukọ Oluwa wa Jesu Kristi si Ọlọrun Baba náà. \v 21 Ẹ maa tẹriba fun ara yin pẹlu ọwọ fun Kristi.