adesinaabegunde_yo_eph_text.../06/12.txt

1 line
350 B
Plaintext
Raw Normal View History

\v 12 Nítorí kii se ẹran ara ati ẹjẹ ni awa mba jijadadi, bikose awọn ijọba, awọn alasẹ, ati awọn alakoso ẹmi ninu okunkun, ati awọn ẹmi buburu ninu awọn ọrun. \v 13 Nitorinaa, ẹ gbe gbogbo ihamora Ọlorun wọ, ki ẹyin kki o lee duro ninu akoko ibi yi, ati lẹyin ti ẹ ba ti se ohun gbogbo tan, lati duro giri.