adesinaabegunde_yo_eph_text.../06/09.txt

1 line
195 B
Plaintext
Raw Normal View History

\v 9 Ẹ̀yin ọ̀gá, ẹ tọ́jú àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ bákannáà. Ẹ máse halẹ̀ mọ́ won. Ẹ kuku mọ wipe oga ẹyin mejeji wa ni ọrun, ko si si ojusaaju pẹlu Rẹ̀