\v 31 "Nítorí ìdí èyí ọkùnrin yóò fi Baba àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, yóò sì darapọ̀ mọ́ ìyàwó rẹ̀, àwọn méjèjì yóò sì di ara kan." \v 32 Òtítọ́ tí ó pamọ́ yìí (jẹ́ èyí tí ó) ga - sùgbọ́n èmi ń sọ nípa Krístì àti ìjọ. \v 33 Síbẹ̀síbẹ̀, ẹnìkọ̀ọ̀kan yín pẹ̀lú gbọ́dọ̀ fẹ́ràn ìyàwó rẹ̀, gẹ́gẹ́bí ara òun tìkárarẹ̀, àti wípé ìyàwó náà gbọ́dọ̀ bọ̀wọ̀ fún ọkọ rẹ̀.