adesinaabegunde_yo_eph_text.../05/25.txt

1 line
524 B
Plaintext
Raw Permalink Normal View History

\v 25 Ẹ̀yin ọkọ, ẹ fẹ́ran àwọn aya yín, gẹ́gẹ́bí Krístì ti se fẹ́ràn ìjọ tí ó sì jọ̀wọ́ ara rẹ̀ fún un. \v 26 Krístì jọ̀wọ́ ara Rẹ̀ fún ìjọ, kí ó ba lee sọọ́ dí mímọ́ lẹ́yìn tí ó ti sọọ́ di mímọ́ nípa íifi omi wẹ̀ẹ́ pẹ̀lú ọ̀rọ̀, \v 27 Kí ó baà le fii fún ara Rẹ̀ gẹ́gẹ́bí ìjọ tí´ ó lógo láìní àbàwọ́n tàbí ìdọ̀tí tàbí irú nkan báwonnì, sùgbọ́n mímọ́ láìní àbùkù.