adesinaabegunde_yo_col_text.../03/05.txt

1 line
583 B
Plaintext

\v 5 Nísìnsinyí, ẹ pa àwọn ẹ̀ya ara yín ti o wa lí aye run: àgbèrè, panságà, ìwà àìmọ, ìgbónára, ìfẹ́kúfẹ̀ àti wọ̀bìà ti ṣe ìbọ̀rìṣà. \v 6 Nítorí àwọn nkan wọ̀nyii ni ìbínú Ọlọrun se nbọ̀ sórí àwọn ọmọ aláìgbọràn. \v 7 Nínú àwọn ǹkan wọ̀nyii ni ẹ̀yin naa tí rin níbàkan ri ni àkókò tí ẹ gbé nínú wọn. \v 8 Sùgbọ́n nísìnsinyìí ẹ gbudọ̀ pa àwọn ǹkan wọnyii tí - ìrunú, ìbìnu, èróngbà ibi, èèbúú, àti ọ̀rọ̀ èèrí kúrò ní ẹnu yín.