adesinaabegunde_yo_col_text.../03/01.txt

1 line
485 B
Plaintext

\c 3 \v 1 Bí ó bá jẹ́ wípé Ọlọrun ti jí yín pẹ̀lu Kristi, ẹ sàfẹ̀ríí awọn nkan ti nbẹ́ loke, níbití Kristi gbé joko pẹ́lu Ọlọrun \v 2 Ẹ ronú àwọn nkan tí nbẹ lókè, ki se àwọn nkan ti nbẹ ní ayé. \v 3 Nítorí ti ẹ ti ku, a sì ti fi ẹ̀mi yín pamọ pẹ̀lu Kristi nínú Ọlọrun \v 4 Nígbàtí Kristi bá fi arahàn, ẹnití tíí ṣe ayé yín, nígbànáà ni eyin náà yio farahàn pẹ̀lu rẹ̀ nínú ògo.