1 line
632 B
Plaintext
1 line
632 B
Plaintext
\v 22 Ẹ̀yin ẹrú, e máa gbọ́ràn sí àwọn olówó yín níti ara lẹ́nu nínú ohun gbógbó, ki se pẹ̀lú ojú-aye, bi awọn ti nfẹ́ lati tẹ̀ ènìyàn lọ́rùn, sùgbọ́n pẹ̀lu ọkàn tí ó tọ́. Ẹ bẹ̀ru Ọlọrun. \v 23 Ohunkóhun ti ẹ bá nsé, ẹ siṣẹ́ láti inú ọkàn gẹ́gẹ́bí fún Olúwa ti kìí si se fún àwọn ènìyàn \v 24 Ẹ̀yín mọ pé ẹ ó gba èrè ogún ìbí láti ọ̀dọ̀ Olúwa. Kristi Olúwa ní ẹ̀yín nsìn. \v 25 Nítorí ẹnikẹ́ni ti ó bá ṣe àisòdodo yio gba èrè fún àisododo ti o ṣe, àti pé kò sí ojúsàájú. |