adesinaabegunde_yo_col_text.../03/18.txt

1 line
454 B
Plaintext

\v 18 Ẹ̀yin ìyàwó, ẹ tẹríba fún àwọn ọkọ yín, gẹ́gẹ́bí ó ti tọ́ nínú Olúwa. \v 19 Ẹ̀yin ọkọ, ẹ fẹ́ran àwọn ìyàwó yín, àti pé kí ẹ má se korò sí wọn. \v 20 Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ràn si àwọn òbí yín lẹ́nu nínú ohun gbogbo, nítorí eyí ní o dára nínú Olúwa. \v 21 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má se máa mu àwọn ọmọ yín bínú, kí wọn má bá rẹ̀wẹ̀sì.