adesinaabegunde_yo_col_text.../01/07.txt

1 line
309 B
Plaintext

\v 7 Eléyìí sì ni ìyìnrere náà bí ẹ̀yin ti kọ́ láti ọ̀dọ Ẹpáfrà, alábàáṣiṣẹ́pọ̀ wa ọ̀wọ́n, ẹnití ó tún ṣe ìránṣẹ́ tòótọ́ ti Kristi ní ipò àwatìkárawa. \v 8 Ẹpáfrà si ti sọ ìfẹ́ tí ẹ̀yin ní nínú Ẹ̀mí di mímọ̀ fún wa.