adesinaabegunde_yo_col_text.../01/04.txt

1 line
671 B
Plaintext

\v 4 Àwá ti gbọ́ nípa ìgbàgbó yín nínú Krístì Jésù àti nípa ti ìfẹ́ tí ẹ̀yín ní sí gbogbo àwọn ènìyaǹ mímọ́ O̩ló̩run. \v 5 Ìfẹ́ yìí ni ẹ̀yín ní nítorí ìrètí tí ó wà ní ìpamọ́ fún yín ní ọ̀run. Ẹ̀yin ti kọ́kọ́ gbọ́ sáájú nípa ìrètí yìí nínú ọ̀rọ̀ òtítọ́, àní ìyìnrere, \v 6 èyítí ó tọ̀ yín wá. Ìyìnrere yìí ń so èso bẹ́ẹ̀ni ó sì ń gbilẹ̀ si ní gbogbo àgbáyé. Bákanńà ni ó sì ń dàgbà nínú yín pẹ̀lú láti ọjọ́ tí ẹ ti gbọ́ tí ẹ sì ti kọ́ nípa oore-ọ̀fẹ́ O̩ló̩run nínú òtítọ́.