adesinaabegunde_yo_col_text.../03/15.txt

1 line
743 B
Plaintext

\v 15 Ẹ jẹ́ kí àlááfíà Krístì jọba ní ọkàn yín. Nítorí ti àlááfíà yìí ni a ṣe pè yín sínú ara kan. Àti pé ẹ máa kún fún ìdúpẹ́. \v 16 Ẹ jẹ́ kí ọ̀rọ̀ Krístì máa gbé inú yín lọ́pọ̀lọpọ̀. Ẹ máa kọ́ni pẹ̀lú ọgbọ́n gbogbo bẹ́èni kí ẹ máa gba ara yín ní ìyànjú pẹ̀lú àwọn Sáàmù àti àwọn orin ìyìn àti àwọn orin ẹ̀mí. Ẹ kọrin pẹ̀lú ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ọpẹ́ nínú ọkàn yín sí Ọlọ́run. \v 17 Ohunkóhun tí ẹ̀yin bá ń ṣe, nínú ọ̀rọ̀ sísọ tàbí nínú ìṣe, ẹ ṣe gbogbo rẹ̀ ní orúkọ Jésù Olúwa. Kí ẹ sì ma fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run Baba nípasẹ Rẹ̀.