1 line
562 B
Plaintext
1 line
562 B
Plaintext
\c 3 \v 1 Bí ó bá jẹ́ wípé Ọlọ́run ti jí yín pẹ̀lú Krístì, ẹ sàfẹẹ́rí àwọn nǹkan tí ń bẹ lókè, níbití Krístì gbé jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún Ọlọ́run. \v 2 Ẹ ronú nípa àwọn nǹkan tí ń bẹ lókè, kìí ṣe àwọn nǹkan tí ń bẹ ní ayé. \v 3 Nítorítí ẹ ti kú, a sì ti fi ẹ̀mí yín pamọ́ pẹ̀lú Krístì nínú Ọlọ́run. \v 4 Nígbàtí Krístì bá fi ara hàn, ẹnití Í ṣe ìyè yín, nígbànáà ni ẹ̀yin náà yó farahàn pẹ̀lú Rẹ̀ nínú ògo. |