1 line
494 B
Plaintext
1 line
494 B
Plaintext
\v 10 A sì ti sọ yín di kíkún nínú Rẹ̀, ẹnití ó jẹ̀ orí lórí gbogbo ipá àti agbára. \v 11 Nínú Rẹ̀ ni a sì kọ ẹ̀yin náà n'ílà pẹ̀lú, ìkọlà tí a kò ti ọwọ́ ènìyàn ṣe níti mímú ẹran ara kúrò, ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí ìkọlà Krístì. \v 12 A ti sin yín pẹ̀lú Rẹ̀ nínú ìrìbọmi, àti nínú Rẹ̀ ni a jí yín dìde nípa ìgbàgbọ́ nínú agbára Ọlọ́run, enití ó jí Krístì dìde nínú òkú. |