adesinaabegunde_yo_col_text.../02/04.txt

1 line
289 B
Plaintext

\v 4 Mo sọ èyí kí ẹnikẹ́ni má baà fi ọ̀rọ̀ dídùn tàn yín jẹ. \v 5 Bótilẹ̀jẹ́'pé èmi ko sí pẹ̀lú yín lójúkojú, síbẹ̀, mo wa pẹ̀lú yín nínú ẹ̀mí. Mo yọ̀ láti mọ ètò dáradára yín àti ìdúróṣinṣin yín nínú Krístì.