Sat Jun 12 2021 19:29:17 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-06-12 19:29:18 +01:00
parent e67ed95224
commit f6fd614ddd
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 15 Òun sì ni àwòrán Ọlọ́run tí a kò rìí, àkọ́bí nínú gbogbo ẹ̀dá. \v 16 Nítorí nínú Rẹ̀ lati ṣẹ̀dá ohun gbogbo, àwọn ohun tí ń bẹ ní àwọn ọ̀run àti àwọn ohun tí ń bẹ ní ayé, àwọn ohun tí à ń rí àti àwọn ohun tí a kò rí. Yálà àwọn ìtẹ́ tàbí àwọn ìjẹgàba tàbí àwọn ìjọba tàbí àwọn agbára, ohun gbogbo ní a dá nípasẹ̀ rẹ̀ àti fún-un. \v 17 Òhun tìkálára rẹ̀ wà sáájú ohun gbogbo, nínú rẹ̀ ní ohun gbogbo sọ̀kan.
\v 15 Òun sì ni àwòrán Ọlọ́run tí a kò rìí, àkọ́bí nínú gbogbo ẹ̀dá. \v 16 Nítorí nínú Rẹ̀ lati ṣẹ̀dá ohun gbogbo, àwọn ohun tí ń bẹ ní àwọn ọ̀run àti àwọn ohun tí ń bẹ ní ayé, àwọn ohun tí à ń rí àti àwọn ohun tí a kò rí. Yálà àwọn ìtẹ́ tàbí àwọn ìjẹgàba tàbí àwọn ìjọba tàbí àwọn agbára, ohun gbogbo ní a dá nípasẹ̀ Rẹ̀ àti fún-Un. \v 17 Òun tìkálára Rẹ̀ wà ṣáájú ohun gbogbo, nínú rẹ̀ ní ohun gbogbo sọ̀kan.