Mon Jun 14 2021 19:53:51 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-06-14 19:53:52 +01:00
parent 4528dd1609
commit f2de1a4f32
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tí ó ń fẹ́ ìwà ìrẹ̀lẹ̀ àbí ìsìn àwọn ángẹ́lì ṣe ìdájọ́ yín kúrò nínú ère yín. Irúfẹ́ ènìyàn báyìí a máa wọnú àwọn ohun tí ó rí àti pé a sì máa gbéraga nípa èro ẹran ara rẹ̀. \v 19 Òun kò sì di orí nnì mú ṣinṣin. Láti ara orí ni gbogbo ẹ̀ya ara pẹ̀lú àwọn oríkèríkèé atí iṣan ti ń gba ìpèsè tí wọ́n si so papọ́; o ndàgbà pẹ̀lú ìdàgbà ti Ọlọrun fi fun.
\v 18 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tí ó ń fẹ́ ìwà ìrẹ̀lẹ̀ àbí ìsìn àwọn ángẹ́lì ṣe ìdájọ́ yín kúrò nínú ère yín. Irúfẹ́ ènìyàn báyìí a máa wọnú àwọn ohun tí ó rí àti pé a sì máa gbéraga nípa èro ẹran ara rẹ̀. \v 19 Òun kò sì di orí nnì mú ṣinṣin. Láti ara orí ni gbogbo ẹ̀ya ara pẹ̀lú àwọn oríkèríkèé atí iṣan ti ń gba ìpèsè tí wọ́n sì so papọọ̀; ó ń dàgbà pẹ̀lú ìdàgbà tí Ọlọ́run fi fún.

View File

@ -1 +1 @@
\v 20 Bi ẹ̀yín ba ti kú pẹ̀lu Kristi si awọn ẹ̀mí ìpìlẹ̀ ayé, kílóṣe ti ẹ̀yín ngbé bí ẹnití a fi ipa mu lati gbọ ti ayé: \v 21 "Má gbamú, tàbí tọ́wò, tàbí fọwọ̀kàn"? \v 22 Gbogbo ìwọ̀nyí ni yio parun pẹ̀lú ìlo wọn, gẹ́gẹ́bí àwọn ìlànà àti ẹ̀kọ́ àwọn ènìyàn \v 23 Àwọn ìlànà yii ni ọgbọn àdábọwọ́ ìsìn àti ìrẹ̀lẹ̀ àti ìpọ́nra-ẹni-lójú. Súgbọ́n wọn kò ni ere láti dín iṣẹ́ ara kù.
\v 20 Bí ẹ̀yín ba ti kú pẹ̀lu Kristi si awọn ẹ̀mí ìpìlẹ̀ ayé, kílóṣe ti ẹ̀yín ngbé bí ẹnití a fi ipa mu lati gbọ ti ayé: \v 21 "Má gbamú, tàbí tọ́wò, tàbí fọwọ̀kàn"? \v 22 Gbogbo ìwọ̀nyí ni yio parun pẹ̀lú ìlo wọn, gẹ́gẹ́bí àwọn ìlànà àti ẹ̀kọ́ àwọn ènìyàn \v 23 Àwọn ìlànà yii ni ọgbọn àdábọwọ́ ìsìn àti ìrẹ̀lẹ̀ àti ìpọ́nra-ẹni-lójú. Súgbọ́n wọn kò ni ere láti dín iṣẹ́ ara kù.

View File

@ -57,7 +57,7 @@
"02-10",
"02-13",
"02-16",
"02-20",
"02-18",
"03-title",
"03-01",
"03-05",